Àwọn Ọba Kinni 11:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bẹ̀rẹ̀ sí bọ Aṣitoreti, oriṣa àwọn ará Sidoni ati oriṣa Milikomu, ohun ìríra tí àwọn ará Amoni ń bọ.

Àwọn Ọba Kinni 11

Àwọn Ọba Kinni 11:1-8