Àwọn Ọba Kinni 11:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹẹdẹgbẹrin (700) ni àwọn obinrin ati ọmọ ọba tí Solomoni gbé níyàwó, ó sì tún ní ọọdunrun (300) obinrin mìíràn. Àwọn obinrin náà sì mú kí ọkàn rẹ̀ ṣí kúrò lọ́dọ̀ Ọlọrun.

Àwọn Ọba Kinni 11

Àwọn Ọba Kinni 11:1-9