Àwọn Ọba Kinni 11:16 BIBELI MIMỌ (BM)

nítorí pé Joabu ati àwọn ọmọ ogun rẹ̀ wà ní ilẹ̀ Edomu fún oṣù mẹfa, títí tí ó fi pa gbogbo àwọn ọkunrin tí wọ́n wà ní ilẹ̀ Edomu run.

Àwọn Ọba Kinni 11

Àwọn Ọba Kinni 11:10-23