Àwọn Ọba Kinni 11:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣáájú àkókò yìí, nígbà tí Dafidi gbógun ti àwọn ará Edomu, tí ó sì ṣẹgun wọn, Joabu balogun rẹ̀ lọ sin àwọn tí wọ́n kú sógun, ó sì pa gbogbo àwọn ọmọkunrin Edomu;

Àwọn Ọba Kinni 11

Àwọn Ọba Kinni 11:14-16