Àwọn Ọba Kinni 11:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Adadi ati díẹ̀ lára àwọn iranṣẹ baba rẹ̀, tí wọ́n jẹ́ ará Edomu sá lọ sí ilẹ̀ Ijipti, Adadi kéré pupọ nígbà náà.

Àwọn Ọba Kinni 11

Àwọn Ọba Kinni 11:7-20