Àwọn Ọba Kinni 10:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó sọ fún Solomoni ọba pé, “Òtítọ́ ni ìròyìn tí mo gbọ́ ní ìlú mi nípa ìjọba rẹ ati ọgbọ́n rẹ.

Àwọn Ọba Kinni 10

Àwọn Ọba Kinni 10:1-14