Àwọn Ọba Kinni 10:5 BIBELI MIMỌ (BM)

irú oúnjẹ tí ó wà lórí tabili rẹ̀, ìjókòó àwọn ìjòyè rẹ̀, ìṣesí àwọn iranṣẹ rẹ̀ ati ìwọṣọ wọn, àwọn tí wọ́n ń gbé ọtí rẹ̀ ati ẹbọ sísun tí ó ń rú ninu ilé OLUWA, ẹnu yà á lọpọlọpọ.

Àwọn Ọba Kinni 10

Àwọn Ọba Kinni 10:1-6