Àwọn Ọba Kinni 10:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn n kò gbàgbọ́ títí tí mo fi wá, tí mo sì fi ojú ara mi rí i. Àwọn tí wọ́n sọ fún mi kò tilẹ̀ sọ ìdajì ohun tí mo rí. Ọgbọ́n, ati ọrọ̀ rẹ pọ̀ rékọjá ohun tí mo gbọ́ lọ.

Àwọn Ọba Kinni 10

Àwọn Ọba Kinni 10:1-10