Àwọn Ọba Kinni 10:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ère kinniun mejila wà lórí àwọn àtẹ̀gùn mẹfẹẹfa, meji meji lórí àtẹ̀gùn kọ̀ọ̀kan, ní ẹ̀gbẹ́ kinni keji àtẹ̀gùn náà; kò sí ìjọba orílẹ̀-èdè kankan tí ó tún ní irú ìtẹ́ náà.

Àwọn Ọba Kinni 10

Àwọn Ọba Kinni 10:14-26