Àwọn Ọba Kinni 10:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìtẹ́ náà ní àtẹ̀gùn mẹfa, ère orí ọmọ mààlúù sì wà lẹ́yìn ìtẹ́ náà. Ère kinniun wà ní ẹ̀gbẹ́ kinni keji ibi tí wọn ń gbé apá lé lára ìtẹ́ náà.

Àwọn Ọba Kinni 10

Àwọn Ọba Kinni 10:9-27