Àwọn Ọba Kinni 10:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Wúrà ni wọ́n fi ṣe gbogbo ife ìmumi Solomoni, ati gbogbo àwọn ohun èlò tí ó wà ninu Ilé Igbó Lẹbanoni. Kò sí ẹyọ kan ninu wọn tí wọ́n fi fadaka ṣe, nítorí pé fadaka kò já mọ́ nǹkankan ní àkókò Solomoni.

Àwọn Ọba Kinni 10

Àwọn Ọba Kinni 10:17-23