Àwọn Ọba Kinni 1:52 BIBELI MIMỌ (BM)

Solomoni dáhùn pé, “Bí ó bá jẹ́ olóòótọ́, ẹnikẹ́ni kò ní fi ọwọ́ kan ẹyọ kan ninu irun orí rẹ̀, ṣugbọn bí ó bá hùwà ọ̀tẹ̀, yóo kú.”

Àwọn Ọba Kinni 1

Àwọn Ọba Kinni 1:45-53