Àwọn Ọba Kinni 1:53 BIBELI MIMỌ (BM)

Solomoni ọba bá ranṣẹ lọ mú Adonija wá láti ibi pẹpẹ. Adonija lọ siwaju ọba, ó sì wólẹ̀. Ọba sọ fún un pé kí ó máa lọ sí ilé rẹ̀.

Àwọn Ọba Kinni 1

Àwọn Ọba Kinni 1:47-53