Àwọn Ọba Kinni 1:51 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n sọ fún Solomoni ọba pé ẹ̀rù rẹ ń ba Adonija ati pé ó wà níbi tí ó ti di ìwo pẹpẹ mú, tí ó sì wí pé, àfi kí Solomoni ọba fi ìbúra ṣèlérí pé kò ní pa òun.

Àwọn Ọba Kinni 1

Àwọn Ọba Kinni 1:47-53