Àwọn Ọba Kinni 1:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Wá, jẹ́ kí n gbà ọ́ nímọ̀ràn kan, bí o bá fẹ́ràn ẹ̀mí rẹ, ati ẹ̀mí Solomoni, ọmọ rẹ.

Àwọn Ọba Kinni 1

Àwọn Ọba Kinni 1:4-13