Àwọn Ọba Kinni 1:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Tọ Dafidi ọba lọ lẹsẹkẹsẹ, kí o sì bi í pé, ṣebí òun ni ó fi ìbúra ṣe ìlérí fún ọ pé Solomoni ọmọ rẹ ni yóo jọba lẹ́yìn rẹ̀? Kí ló dé tí Adonija fi di ọba?

Àwọn Ọba Kinni 1

Àwọn Ọba Kinni 1:5-18