Àwọn Ọba Kinni 1:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Natani bá tọ Batiṣeba ìyá Solomoni lọ, ó bi í pé, “Ṣé o ti gbọ́ pé Adonija ọmọ Hagiti ti fi ara rẹ̀ jọba, Dafidi ọba kò sì mọ nǹkankan nípa rẹ̀.

Àwọn Ọba Kinni 1

Àwọn Ọba Kinni 1:9-21