Àwọn Ọba Keji 9:35 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọkunrin tí wọ́n lọ sin òkú náà kò rí nǹkankan àfi agbárí, ati egungun ọwọ́ ati ti ẹsẹ̀ rẹ̀.

Àwọn Ọba Keji 9

Àwọn Ọba Keji 9:33-37