Àwọn Ọba Keji 9:36 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n pada wá sọ ohun tí ó ṣẹlẹ̀ fún Jehu, ó ní, “OLUWA ti sọ tẹ́lẹ̀ láti ẹnu wolii Elija, iranṣẹ rẹ̀ pé, ajá ni yóo jẹ òkú Jesebẹli ní agbègbè Jesireeli.

Àwọn Ọba Keji 9

Àwọn Ọba Keji 9:30-37