Àwọn Ọba Keji 9:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, ó wọlé, ó jẹ, ó mu, lẹ́yìn náà, ó ní, “Ẹ lọ sin òkú obinrin ẹni ègún yìí nítorí pé ọmọ ọba ni.”

Àwọn Ọba Keji 9

Àwọn Ọba Keji 9:24-37