Àwọn Ọba Keji 8:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó pada sí ìlú Jesireeli, ó lọ wo ọgbẹ́ náà sàn. Ahasaya, ọba Juda, ọmọ Jehoramu, sì lọ bẹ̀ ẹ́ wò ní Jesireeli.

Àwọn Ọba Keji 8

Àwọn Ọba Keji 8:25-29