Àwọn Ọba Keji 8:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Ahasaya bá Joramu, ọba Israẹli lọ, wọ́n gbógun ti Hasaeli, ọba Siria, ní Ramoti Gileadi. Àwọn ọmọ ogun Siria ṣá ọba Joramu lọ́gbẹ́.

Àwọn Ọba Keji 8

Àwọn Ọba Keji 8:27-29