Àwọn Ọba Keji 9:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Eliṣa pe ọ̀kan ninu àwọn ọmọ àwọn wolii, ó sọ fún un pé, “Ṣe kánkán, kí o lọ sí Ramoti Gileadi pẹlu ìgò òróró yìí.

Àwọn Ọba Keji 9

Àwọn Ọba Keji 9:1-8