Àwọn Ọba Keji 4:40 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bu oúnjẹ fún àwọn ọmọ wolii láti jẹ. Bí wọ́n ti ń jẹ àsáró náà, wọ́n kígbe pé “Eniyan Ọlọrun, májèlé wà ninu ìkòkò yìí!” Wọn kò sì lè jẹ ẹ́ mọ́.

Àwọn Ọba Keji 4

Àwọn Ọba Keji 4:38-44