Àwọn Ọba Keji 4:41 BIBELI MIMỌ (BM)

Eliṣa dáhùn, ó ní, “Ẹ bu oúnjẹ díẹ̀ wá.” Ó da oúnjẹ náà sinu ìkòkò, ó sì wí pé, “Bu oúnjẹ fún àwọn ọkunrin náà, kí wọ́n lè jẹun.” Kò sì sí oró májèlé ninu oúnjẹ náà mọ́.

Àwọn Ọba Keji 4

Àwọn Ọba Keji 4:34-44