Àwọn Ọba Keji 4:39 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọ̀kan ninu àwọn iranṣẹ náà lọ sí oko láti já ewébẹ̀, ó rí àjàrà tí ó máa ń hù ninu igbó, ó sì ká ninu èso rẹ̀. Nígbà tí ó dé ilé, ó rẹ́ wọn sinu ìkòkò àsáró náà láìmọ̀ ohun tí wọ́n jẹ́.

Àwọn Ọba Keji 4

Àwọn Ọba Keji 4:36-44