Àwọn Ọba Keji 4:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó kígbe pe ọkọ rẹ̀ pé, “Jọ̀wọ́ rán iranṣẹ kan sí mi pẹlu kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ kan. Mo fẹ́ sáré lọ rí eniyan Ọlọ́run, n óo pada dé kíákíá.”

Àwọn Ọba Keji 4

Àwọn Ọba Keji 4:18-30