Àwọn Ọba Keji 4:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Obinrin náà bá gbé òkú ọmọ náà lọ sí yàrá Eliṣa, ó tẹ́ ẹ sí orí ibùsùn rẹ̀, ó ti ìlẹ̀kùn, ó sì jáde.

Àwọn Ọba Keji 4

Àwọn Ọba Keji 4:12-27