Àwọn Ọba Keji 4:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí iranṣẹ náà gbé ọmọ náà dé ọ̀dọ̀ ìyá rẹ̀, ìyá rẹ̀ gbé e lé ẹsẹ̀ títí ọmọ náà fi kú ní ọ̀sán ọjọ́ náà.

Àwọn Ọba Keji 4

Àwọn Ọba Keji 4:18-23