Àwọn Ọba Keji 4:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Lójijì, ó kígbe pe baba rẹ̀, ó ní, “Orí mi! Orí mi!”Baba rẹ̀ sì sọ fún iranṣẹ kan kí ó gbé ọmọ náà lọ sọ́dọ̀ ìyá rẹ̀.

Àwọn Ọba Keji 4

Àwọn Ọba Keji 4:16-20