Àwọn Ọba Keji 4:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ kan, lẹ́yìn tí ọmọ náà dàgbà, ó lọ bá baba rẹ̀ ninu oko níbi tí wọ́n ti ń kórè.

Àwọn Ọba Keji 4

Àwọn Ọba Keji 4:12-22