Àwọn Ọba Keji 4:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn obinrin náà lóyún ó sì bí ọmọkunrin ní akoko náà ní ọdún tí ó tẹ̀lé e gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ Eliṣa.

Àwọn Ọba Keji 4

Àwọn Ọba Keji 4:8-20