Àwọn Ọba Keji 4:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọkọ rẹ̀ bèèrè lọ́wọ́ rẹ̀ pé, “Kí ló dé tí o fi fẹ́ lọ rí i lónìí? Òní kì í ṣe ọjọ́ oṣù tuntun tabi ọjọ́ ìsinmi.”Ó sì dáhùn pé, “Kò séwu.”

Àwọn Ọba Keji 4

Àwọn Ọba Keji 4:20-26