Àwọn Ọba Keji 3:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn ará Moabu gbọ́ pé àwọn ọba mẹtẹẹta ń bọ̀ láti gbógun tì wọ́n, wọ́n pe gbogbo àwọn tí wọ́n lè lọ sógun jọ, ati àgbà ati ọmọde, wọ́n sì fi wọ́n sí àwọn ààlà ilẹ̀ wọn.

Àwọn Ọba Keji 3

Àwọn Ọba Keji 3:15-24