Àwọn Ọba Keji 3:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n jí ní òwúrọ̀ ọjọ́ keji, tí oòrùn ń ràn sórí omi náà, àwọn ará Moabu rí i pé omi tí ó wà níwájú àwọn pọ́n bí ẹ̀jẹ̀.

Àwọn Ọba Keji 3

Àwọn Ọba Keji 3:14-27