Àwọn Ọba Keji 3:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ keji, ní àkókò ìrúbọ òwúrọ̀, omi ya wá láti apá Edomu, títí tí gbogbo ilẹ̀ fi kún fún omi.

Àwọn Ọba Keji 3

Àwọn Ọba Keji 3:11-24