Àwọn Ọba Keji 3:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ óo ṣẹgun àwọn ìlú olódi ati àwọn ìlú dáradára wọn, ẹ óo gé gbogbo igi dáradára, ẹ ó dí gbogbo orísun omi wọn; ẹ óo sì da òkúta sí gbogbo ilẹ̀ oko wọn.”

Àwọn Ọba Keji 3

Àwọn Ọba Keji 3:12-22