Àwọn Ọba Keji 25:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó sun ilé OLUWA níná, ati ilé ọba ati gbogbo ilé tí ó wà ní Jerusalẹmu. Gbogbo àwọn ilé ńláńlá tí ó wà níbẹ̀ ni ó sì dáná sun.

Àwọn Ọba Keji 25

Àwọn Ọba Keji 25:5-16