Àwọn Ọba Keji 25:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn ọmọ ogun Kalidea, tí wọ́n wà pẹlu olórí àwọn tí wọn ń ṣọ́ ọba wó gbogbo odi Jerusalẹmu lulẹ̀ patapata.

Àwọn Ọba Keji 25

Àwọn Ọba Keji 25:2-13