Àwọn Ọba Keji 25:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Nebusaradani kó àwọn tí wọ́n kù láàrin ìlú ati àwọn tí wọ́n sá tọ ọba Babiloni lọ, pẹlu ogunlọ́gọ̀ àwọn yòókù lọ sí ìgbèkùn.

Àwọn Ọba Keji 25

Àwọn Ọba Keji 25:5-18