Àwọn Ọba Keji 25:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ keje oṣù karun-un ọdún kọkandinlogun ìjọba Nebukadinesari, ọba Babiloni, Nebusaradani, tí ń ṣiṣẹ́ fún ọba Babiloni, tí ó sì tún jẹ́ olórí àwọn tí ń ṣọ́ Babiloni wá sí Jerusalẹmu.

Àwọn Ọba Keji 25

Àwọn Ọba Keji 25:2-14