Àwọn Ọba Keji 25:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n pa àwọn ọmọ Sedekaya lójú rẹ̀, lẹ́yìn náà ni Nebukadinesari ọba yọ ojú Sedekaya, ó fi ẹ̀wọ̀n dè é, ó sì mú un lọ sí Babiloni.

Àwọn Ọba Keji 25

Àwọn Ọba Keji 25:1-10