Àwọn Ọba Keji 24:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìjìyà yìí dé bá Juda láti ọ̀dọ̀ OLUWA, láti pa wọ́n run kúrò níwájú rẹ̀, nítorí ìwà ẹ̀ṣẹ̀ Manase ọba,

Àwọn Ọba Keji 24

Àwọn Ọba Keji 24:1-4