Àwọn Ọba Keji 24:4 BIBELI MIMỌ (BM)

ati nítorí ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ tí ó ti ta sílẹ̀, nítorí tí ó ta ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ sílẹ̀ ní gbogbo ìgboro Jerusalẹmu, OLUWA kò ní dáríjì í.

Àwọn Ọba Keji 24

Àwọn Ọba Keji 24:1-13