Àwọn Ọba Keji 24:2 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA bá rán àwọn ọmọ ogun Kalidea, ati ti Siria, ti Moabu, ati ti Amoni, láti pa Juda run bí ọ̀rọ̀ ti OLUWA sọ láti ẹnu àwọn wolii, iranṣẹ rẹ̀.

Àwọn Ọba Keji 24

Àwọn Ọba Keji 24:1-8