Àwọn Ọba Keji 24:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní àkókò ìjọba Jehoiakimu ni Nebukadinesari, ọba Babiloni gbógun ti Jerusalẹmu, Jehoiakimu sì di iranṣẹ rẹ̀ fún ọdún mẹta. Lẹ́yìn náà, ó pada lẹ́yìn Nebukadinesari, ó sì ṣọ̀tẹ̀ sí i.

Àwọn Ọba Keji 24

Àwọn Ọba Keji 24:1-4