Àwọn Ọba Keji 24:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, OLUWA bínú sí Jerusalẹmu ati Juda; ó sì lé wọn kúrò níwájú rẹ̀.Sedekaya sì ṣọ̀tẹ̀ sí ọba Babiloni.

Àwọn Ọba Keji 24

Àwọn Ọba Keji 24:13-20