Àwọn Ọba Keji 25:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ kẹwaa oṣù kẹwaa ọdún kẹsan-an ìjọba rẹ̀, Nebukadinesari, ọba Babiloni, òun ati àwọn ọmọ ogun rẹ̀ gbógun ti Jerusalẹmu, wọ́n dó tì í, wọ́n sì mọ odi yí i ká.

Àwọn Ọba Keji 25

Àwọn Ọba Keji 25:1-8