Àwọn Ọba Keji 23:35 BIBELI MIMỌ (BM)

Jehoiakimu ọba gba owó orí lọ́wọ́ àwọn eniyan gẹ́gẹ́ bí ọrọ̀ wọn ti pọ̀ tó, láti rí owó san ìṣákọ́lẹ̀ fún ọba Ijipti gẹ́gẹ́ bí ó ti pa á láṣẹ fún un.

Àwọn Ọba Keji 23

Àwọn Ọba Keji 23:27-37