Àwọn Ọba Keji 23:36 BIBELI MIMỌ (BM)

Jehoiakimu jẹ́ ẹni ọdún mẹẹdọgbọn nígbà tí ó jọba, ó sì jọba ní Jerusalẹmu fún ọdún mọkanla. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Sebida, ọmọ Pedaaya, láti ìlú Ruma.

Àwọn Ọba Keji 23

Àwọn Ọba Keji 23:26-37